Awọn Ojuse Musulumi si ara wọn
Share:

Listens: 1

About

Ibanisọrọ yii sọ daradara ti o yẹ ki o maa ti ọwọ musulumi kan jade si ọdọ musulumi keji ati awọn aburu ti o yẹ ki wọn maa le jina si ara wọn.