Awọn Ohun Eewọ ti apakan ninu awọn Musulumi fi ọwọ yẹpẹrẹ mu
Share:

Listens: 1

About

Idanilẹkọ nipa awọn ohun eewọ ti o ti di gbajumọ ni awujọ wa ni ode oni pẹlu ẹri ikilọ awọn iwa ibajẹ yii lati inu Alukuraani ati Sunnah Anabi.