Awọn Ekọ ti o rọ mọ sise Igbansẹ (Itọ ati Igbẹ)
Share:

Listens: 1

About

Alaye lori awọn ekọ ati awọn ohun ti o je dandan fun musulumi lati se nigbati o ba fẹ se igbansẹ, ọrọ si tun waye lori awọn aaye ti a kọ fun ni lati se igbansẹ si.